Ka Ma Ma Ri

Tope Alabi

From ORO (2025)

2025

Ka ma ma ri lai oPe iyin re tan lenu miEmi ayin o lowuroEmi ayin o losanEmi ayin o lasale oIyin re o ni tan lenu mi
Oluwa oluwa wa Olorun awon omo ogunOpolopo iriri nile aye nbi lo le gba iyin re lenu omo eniyanIponju je kan ninu won, aitete resi adura o je kan ninu wonKeda ma sise oju meji bi ko tun ma ri bi oleIyen tun je kan ninuAmo ninu ohun gbogbo taba nla koja nile aye nbi Olorun majemu oO de jo ko wa ba tin mu iyin jade ninu ilakoja tori fun gba die niOti nyin Olorun nigbakan koyin Olorun moMa ma je ko je ipin miAye ti mo mi mo iyin re Olorun miIyin re o ni tan lenu mi oko mi
Ajanto tori ka ye le fe ohunO fo rere eniyan kaakiriO san ko fun oloko, osan ogba fun ologbaO gbe gba aje polowo tan tanSugbon nijo to soko peye leyin oja, to ba aremo loriIjo na lo te lowo eniyanOloko bu, oloja saKo mo pe eni aye n fe lero nteleOju temi gbe soke yi oo, mi o ni wole lai laiIranwo mi towo e wa, ohun la naga yin temiOhun lo ko owo mi nijaMaa yin in, mi o sini teLowuro losan laasaleEmi oni dake iyin re oo, o di lailai pongba
Ohun oju mi ri lajo okunkun kin to di imoleEnu mi ole so tanKi ni mo fe fi san ore gan feni to somi di mole atankayeIyin ogbodo tan lenu miFeni to fara re fun miMele mele gbagbe O oloore oMele mele gbagbe Eni to seyi fun miEyi ofun mii tire ni, n o fi yin o nigba gbogboEni to layemi, to nigba mi, ka ma ri ti n o fi dake

Lyrics are the property and copyright of their respective songwriters, artists and publishers. Shown here to help readers connect songs with Scripture.

Discussion

Loading the discussion…

More by Tope Alabi

Hear a Verse We Missed?