War
Written by Tope Alabi / TY Bello
Aa direct quoteAa allusionAa concept
This is what I hear in my spiritE dide togun togunE dide tija tijaE dide alagbaraDide Olorun miKo wa se'ranwo fokan miDide togun togunOlori ogunAkanda ogunAsaju ogunAkehin ogun laboDide alagbaraDide oni'moleDide alagbaraKo wa se'ranwo fokan waAwa o mo yin uruko melo la mo tale pe oGbogbo araiye iba mo ori ki re won ba ma kpe o ni gbogbo o jo ni Alagbara asaju okun la lo a kehin okun la boGbingbinikin ojijifi aji kpo o jo iku da okpa kun wo kon yeJi kan lu kan kpa olowo ori aiye oni korkoro aiye lo woEji pota bi koiyin gi o jo kpo ke bi ko yegere be ni o oke yo sha ibare oke ti o yeIwo ni oke nla aaa arogun ma ti di o arabataribiti aribiti rababa alejo ti sho ni le kun ni kese oni le kaya ka joAlabe Noah sa si alabe be le asa wa gbanigbani lo jo ogun le ko gbe omo nija asa omo da je ko gbe omo nija asa omo do oshoKorkoro inu aiye korkoro ode aiye ilekun korkoro ati kankun ati wole tinu ile ti ta ode kabiyiesi olodumare pata pata gbogbo oporogodoO ro godo gan asiri aiye owun orun o ro godo gan asiri angeli asiri agbagba mele logun o ro godo gan asiri isale ile asiri ile pepe asiri inu awon ofurufuruKabiyiesi o olo bi owo bi omi o koja owo aso o wo ja te leke lo olori aiye gbogbo olori eda gbogbo olori angeliOba eniyan oba eda gbogbo olori awon agbagba mele logun awon orun won kpo lo repete iwo ni kan ni oga gbogbo won emi inu awon woli mimoAda tan atobi tan o koja kika te ekoja riri gigun lai lopin ahile tuwo adan ro adan so adan se olu inu awon orun oke nla o kabiyesi oooo a a gbe o ga
Lyrics are the property and copyright of their respective songwriters, artists and publishers. Shown here to help readers connect songs with Scripture.
Discussion
Loading the discussion…




